Mo gba ìjápọ̀ fídíò yìí láti ọ̀dọ̀ ọ̀rẹ́ mi kan, Clare Connolly. Mo gbà bẹ́ẹ̀, fídíò tó dára ni, mo sì nírètí pé ẹ fẹ́ràn èyí gan-an gẹ́gẹ́ bí mo ṣe fẹ́ràn rẹ̀. Mo ti fi ránṣẹ́ sí gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ mi nípasẹ̀ ìmeeli.
http://www.youtube.com/watch?v=aUaInS6HIGo